Internet Radio about and for ALL YORUBA PEOPLE. For communication that is independent, and respectful; Information about Yoruba people, culture and happenings; In cooperation for the development of Yoruba and African People Worldwide. In Yoruba: Etegbero Yoruba Oduduwa Redio- YO Redio Redio lori Intaneti nipa ati fun GBOGBO OMO YORUBA. Fun ibaraenisoro ninu ominira ati ibowofunraeni; Iroyin ati eko nipa enia, asha ati oniruru ishele laarin Yoruba; Pelu ifowosowopo fun itesiwaju awon enia Yoruba ati Afirika